Taj Mahal ( /ˈtɑːdʒ/ or /ˈtɑːʒməˈhɑːl/; Híndì: ताज महल, lati ede Persia/Urdu: تاج محل "ile ade" ("crown of buildings"), pípè [ˈt̪aːdʒ mɛˈɦɛl]; lasan bi "the Taj") je mausoleum kan ni Agra, India. O je ikan ninu awon ile to see damo lagbaye. O je kiko latowo Shah Jahan obaluaye Mughal gege bi iranti iyawo re keta, Mumtaz Mahal. O je gbigba bi ikan larin awon ile elewa julo lagbaye ati bi ami ife ayeraye.